Gbajúgbajà olórin ti orílè èdè Nìjíríà, Timi Dakolo ti pín àwòrán ìyàwó rè àti àwon omo rè méta ní ìlú London, ó ko síbè wípé “wón tun ti dé baba wón tún ti dé”. Timi Dakolo ti ó jé omo ...
Read More »Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó kéreké parí ilé-èkó gíga ifáfatì ti ìlú ìbàdàn (university of Ibadan).
Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó, Oba Lamidi Adeyemi kékeré, ti parí ifáfitì ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Ibadan tí a mò sí University of Ibadan. Bí omo bá dára ká so, ó ye kí á yé olorì sí ...
Read More »Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran)
Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran) Àbádòfin kan ti kalẹ̀ ní ìlú Rio Grande do Sul ní ilẹ̀ Braṣil tí yô ká àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ aláwọ̀dúdú lọ́wọ́kò láti máa ...
Read More »Labalaba
Ope, Awo Labalaba Adifa fun Labalaba Eyi tii se Ojise Olódùmarè Ope ni won ni ki o maa se A ni t’inu t’eyin mi re o, Olódùmarè Labalaba kii sede A ni t’inu t’eyin mi re o, Olódùmarè Gratitude, ...
Read More »ÈSÙ (Olá ìlú, Bàkeré, Oláàróyè)
Keesu gbà, kebo óda félébo Adia’fun òyìnbó olomo atùkólókò Olomo agberebete lori irebete Njé ìgbà Òrúnmìlà fòrúlá jekà Kéésù gbà, kebo oda felebó Praise~ Olórógun òde Láaróyè agòngò lagò Alamulamu bata Ofebata kojo lamulamu, seketepere Onile ojude,okunrin firifiri japi ...
Read More »Yoruba heart and mind in a Frenchman’s body!
Remembering Pa Pierre Fátúmbí Verger, the polymath… Pa Pierre Fátúmbí Verger was born French into a noble lineage and this great man devoted more than half of his 93-year life to the study, promotion, development and practice of Yoruba culture. ...
Read More »Photo: Araba Adisa Mokorowale with Prof. Moyo Okediji July 26, 2017.
Adieu He was never stingy with his knowledge without asking for a penny. He was patient, kind and nurturing. He taught me more than I could handle and gave me unfettered access to his entire resources. Ó di gbéré Ó ...
Read More »A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè
A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè. Gbogbo àdáwọ́lé wa ló máa yọrí sí rere. Aboyún ilé á bí wẹ́rẹ́, àgàn á tọwọ́ àlà bọ osùn. Gbogbo ẹni tó ń ṣòwò yó jèrè, ...
Read More »Himba, the Namibia Race that Offers S3x To Guests
The interesting and unique people of the Himba race inspired the character ‘Binti’ in Nnedi Okorafor’s novella trilogy ‘Binti’. Many fascinating facts about the Himba people, who are also the most photographed race in Africa, make it imperative to meet ...
Read More »Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.
Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè. Olúsèse, Àràbà àgbáyé ti dágbére wípé Ó dígbà fún aráyé, baba ti lo rè é bá àwon baba ńlá rè ní ìwàlè àsà. Ó ...
Read More »