Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntum. Olórin, peter Okoye tí a mò sí Mr.P tí ó ti fi èkejì rè sílè, Paul Okoye àti alákoso won, Jude Okoye ti gba alákoso tuntun. Ó sì ti ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntun
Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntum. Olórin, peter Okoye tí a mò sí Mr.P tí ó ti fi èkejì rè sílè, Paul Okoye àti alákoso won, Jude Okoye ti gba alákoso tuntun. Ó sì ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Tunde Demuren, Ebuka àti ìyàwó rè ti wo okò òfurufú (jet) láti lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W.
Gbajúgbajà ni, òtòkùlú ni, captain Tunde Demuren tí ìnagije rè n jé OAP, oko toolz ti gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán yí nígbà tí won wo okò òfurufú lo sí Capetown láti péjú pésè níbí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon onísé abe; bàbá kan ní orílé èdè Nàíjíríà àti omo rè obìnrin ti se isé abe lórí aláìsàn won .
Ò n lò èro ayélujára (Facebook) Bucandy Ayo Abubakar, tí ó jé onísé abe pín àwòrán ara rè àti bàbá rè àti bàbá rè onísé abe ti se isé-abe fún aláìsàn kan tí ó ní àìsàn “Appendix” ó sì ko ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.
Ìgbéyàwó eka-èkó (departmental weeding) ni, ìgbéyàwó àgùnbánirò ni tí ó bèrè láti e n lé di e pèlé, tí won wá di orè tímótímó eka-èkó tí won sì padà di olólùlé eka-èkó báyìí ó ti di ìgbéyàwó eka-èkó. Ihekuna Ann ...
Read More »Lolade Comments Off on Wizkid’s 2nd Babymama, Binta Shades Him After He Acknowledged His 3rd Son
Wizkid’s alleged second baby mama, Binta has declared that she wasn’t the reason for Wizkid and Tania Omotayo’s infamous breakup. All of it started 2 days ago, when Binta threw a shade to Wizkid, after he confirmed he welcomed a ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .
Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù . Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on olópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà látàrí aso ìwòkuwò tí won wò.
Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on ” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè.
” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè. Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare. Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú Ekan Egonmwa. Ó sì ti se ayeye ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ota ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa kèké kan ní ìpínlè River.
Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won. Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more