Home / News From Nigeria / Breaking News (page 207)

Breaking News

Destiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.

Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.

Read More »

Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì ba yò.

    Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.  

Read More »

Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.

Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.

Read More »
buy btc cheap in nigeria

Bitcoin hits ₦2.91M ($8,000) Following Massive BCH Surge

Bitcoin just surmounted the ₦2.91M ($8,000) level, topping out at ₦2.919 ($8,020)on Bitfinex before retreating to ₦2.876 ($7,900) at press time. Right now, reading about Bitcoin’s breach of its previous high may be getting repetitious, so strong gets the currency’s bull run been. This time around ...

Read More »

Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.

  Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.

Read More »

Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .

   Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .

Read More »

Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.

Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.

Odára àbí kò dára?

Read More »

Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.

    Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...

Read More »

Akpororo àti ìyàwó rè Josephine Ijeoma Onuabughuchi se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.

Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.  

Read More »

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb