Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.
Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.
Odára àbí kò dára?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.
Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Akpororo àti ìyàwó rè Josephine Ijeoma Onuabughuchi se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.
Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán olópàá tí ó n só Afárá Apogbon (Apogbon Bridge).
Wón ti so síwájú télè wípé àwon olópàá Nàíjíríà n sisé takuntakun láti só agbègbè Apogbon bridge tí a mò fún àwon dánàdánà.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Omodé yìí mà ní opolo oo.
Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ódára kí èèyàn San ìdàméwàá, D’banj ni ó so béè .
D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Cristiano Ronaldo àti Georgina Rodriguez kí omobìnrin káàbò, Alana Martina .
Cristiano Ronaldo ti kí omo rè kerin káàbò, Alana Martina ni orúko rè. E kú oríre Ooo.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more