Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì ba yò.
Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »scully009 Comments Off on Bitcoin hits ₦2.91M ($8,000) Following Massive BCH Surge
Bitcoin just surmounted the ₦2.91M ($8,000) level, topping out at ₦2.919 ($8,020)on Bitfinex before retreating to ₦2.876 ($7,900) at press time. Right now, reading about Bitcoin’s breach of its previous high may be getting repetitious, so strong gets the currency’s bull run been. This time around ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.
Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.
Odára àbí kò dára?
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.
Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Akpororo àti ìyàwó rè Josephine Ijeoma Onuabughuchi se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.
Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more