Home / Art / Àṣà Oòduà / A té o náá…
ona

A té o náá…

A té o náá.
Hee, a té o náá.
Kí o tún ara e té o.
Awo kì nlé ikún.
Awo kì nlé ejò o.
A té o náá kí o tún ara e té.
Awo kì nsúré gun igi òkókó o
A té o náá kí o tún ara e té.
Kí o má fi ìbá nté ode won ìdì wò.
A té o náá kí o tún ara e té.
Bi odò ba kún kí o má mà wó wò o.
A té o náá kí o tún ara e té.
Bí igbá ba já kí o má mà wó wò o.
A té o náá kí o tún ara e té.

Nós te iniciamos.
Nós te iniciamos.
Que você faça sua própria iniciação.(tenha consciência de seus próprios limites)
Um iniciado não se atreve a caçar ikún sem armas.
Um iniciado não se atreve a caçar cobra sem armas.
Nós te iniciamos para que você tenha consciência de seus limites.
Um iniciado não se atreve a subir correndo
em uma árvore de Òkókó.
Nós te iniciamos para que vc tenha consciência de seus limites.
Um iniciado não se atreve a caçar sem ser um bom caçador.
Nós te iniciamos para que vc tenha consciência de seus limites.
Quando o rio estiver muito cheio não se atreva a mergulhar sem saber nadar.
Nós te iniciamos para que vc tenha consciência de seus limites.
Se a corda estiver rompida não suba na árvore.
Nós te iniciamos para que vc tenha consciência de seus limite

Oluwo Ifagbamila Onifade

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...