Home / Art / Àṣà Oòduà / Àbíkéyìn gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná.
dbanj son

Àbíkéyìn gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná.

omokùnrin gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj tí orúko omo náà ń jé Daniel ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná tí a mò sí ojó kerìnlélógún osù kerin odún yii.

Kí olúwa kí ó bá wa rò wón lókàn.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti