Home / Art / Àṣà Oòduà / Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
arewa toni

Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun

Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo
eleyi ti o ku die ko dojubole.
Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo
re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo
sipo. Laipe yi ni edeaiyede bee sile larin awon
ololufe naa ti Afeez owo si ko eru kuro nile fun
iyawo re. sugbon ni bayi, Olorun ti n da si arin awon
ololufe naa ti nkan si ti n pada bo sipo.
Ninu atejise ti Mide fi sita lori eka Intagramm re,
eleyi ti o lo bayi wipe:
“iji naa ti pari!!!… mo dupe lowo Olorun fun
imupadabosipo!!… mo si dupe lowo gbogbo eyin
ololufe ati gbogbo eyin afenifere… Modupe fun adura
yin ati ati iduroti wa… mo dupe lowo yin gidigidi……
@officialafeezowo….. o kii n se oko nikan….. sugbon
Angeli alaabo mi lo je…. o se ti o n wa nibe pelumi ni
gbogbo igba…. titi aye ni emi yio maa ni ife re!!!.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti