Home / Art / Àṣà Oòduà / Àfi kí á ma dúpé.

Àfi kí á ma dúpé.

Àfi kí á ma dúpé .

Ìwo tí o wà láyé
Tí ò ń jeun àsìkò
Tí o tún ń wo aso àsìkò
Ó tó kí olúwa rè sopé

Olúwa tún wá ba o se é
Ó tún fún o n’ílé kó,ó ye kí ó dúpé
Ó tún ra okò bògìní tó tún l’óyé nínú o jé máa dúpé .

Àwon kan rèé
Tí won ń jó jàgíní yòdò
Látàrí okò tí kò dápé
Won sì tún ń sopé
Wípé olúwa Oba dá àwon lólá.

Èwi ń dúpé tèmi ooo.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti