Home / Art / Àṣà Oòduà / Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé yí fé fo ònà sí òdì kejì kí ó tó di wípé àgbàrá gbé won ló.
Kí olúwa té won sí aféfé rere.

Àwòrán nkan níyì nínú àwon méjèèjì.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti