Home / News From Nigeria / Breaking News / Aláìsàn kan kú látàrí ìdádúró láti owó àwon Dókítà tí ó da isé sílè ní ìpínlè Imo.

Aláìsàn kan kú látàrí ìdádúró láti owó àwon Dókítà tí ó da isé sílè ní ìpínlè Imo.

Arákùnrin kan tí a dá mò sí Ogbonna Otu tí ìnagije rè ńjé OJB, ti gbé èmí mì nígbà tí ó kérora orí fífó tí ó l’ágbára.
Gégé bí Òré olóògbé se so, a yára gbé okùnrin yí dìgbàdìgbà lo sí ilé-ìwòsàn léyìn tí ó kérora tán, sùgbón àwon Dókítà kò tètè yà si láti tójú rè látàrí dída isé sílè àwon Dókítà orílè èdè yí. A tún gbó wípé wón ní kí won gbe lo sí ilé-ìwòsàn míràn tí a mò sí Akwakuma ní Owerri, ìjoba ìpínlè Imo. Ilé-ìwòsàn yí ni ó kú sí nígbà tí won gbáà tán. Kí olórun te sí aféfé rere…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti