Home / Art / Àṣà Oòduà / Alágbárí òdómokùnrin kan tí a mò sí yahoo boy lo omo ègbón rè okùnrin tí kò ju omo odún méje lo láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó .

Alágbárí òdómokùnrin kan tí a mò sí yahoo boy lo omo ègbón rè okùnrin tí kò ju omo odún méje lo láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó .

    Òdómokùnrin kan ni owó àwon agbófinró tè nígbà tí ó n lo omokùnrin ègbón rè láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó.

Gégé bí a se gbó, orúko òdómokùnrin tí a fi èsùn kan ni Tunde Owolabi tí ìnagije rè n jé owó n sòrò ( money talk) . Owó ti tè é nígbà tí ó n lo omokùnrin ègbón rè tí ó jé obìnrin tí ó jé omo odún méje lówó ní ìlú Ikoyi ní ìpínlè Eko . Ó wà ní àhámó àwon olópàá báyìí….

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti