Home / Art / Àṣà Oòduà / E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

   Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára bí eni máa kú, kí won bò wá lówó àti kí á fi àkókò sòfò láti múra láti fi dàbí egbin, kí a sì gba èbùn gbàngba ! Sí ò .

Eni tí ó gba òdómobìnrin arewà jùlo àti òdómokùnrin arewà jùlo ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èko ní odún 2014 gba okò bògìnì tí eni tí ó sì mo ìwé jù gba èbún laptop.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo15102024

#Masoyinbo Episode Sixty-Five: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture.