Arabirin oloyun yii lomo bere si ni mu lonii nigboro ilu China. Awon eniyan ti won lo ni won sare se iranlowo fun un. Won pe obirin noosi kan ti n be nitosi won, arabirin noosi naa si bo soju ise lowo kan. Alaafia ni omo tuntun naa wa bayii gege bi telifisan CCTV tilu China se gbe si mi leti.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

