Home / Art / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.

Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.

Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu tí ó ti mu.
Won ti kìlò títí e kò gbó, ojó wo gan ni e to fékun ìmúkúmu tí kò se ara lóore. P

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...