
Ameh Rose ni ó se ipò keta tí Dunu sì se ipò kejì.
Gégé bí iwé ìròyìn daily times se se agbáterù rè, àjòdún tí ó máa n wáyé ní odoodún yí wáyé ní ilé ìtura ní ìlú Eko tí a mò sí Eko hotel. Òpòlopò àwon gbajúgbajà ènìyàn ni ô sì lo fún ojú lóúnje níbè.
Àwon Adájó ibè náà ni Rita Dominic, Ruchard Mofe Damijo, Olisa Adibua, Leesi Peter Vigbooro, Konye Nwabogor, Fade Ogbunro àti béè béè lo.
Ebuka àti Kayla Oniwo ni ó sì se agbáterù rè.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

