Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí ó ti ń pa àwon ará ìlú rè ni owó ti bà tí won sì ti fi se èsin Abia.

Arábìnrin tí ó ti ń pa àwon ará ìlú rè ni owó ti bà tí won sì ti fi se èsin Abia.

Gégé bí ìròyìn se so, arábìnrin tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí tí ó wá láti Amuda Isuochi ní ìpínlè Abia, ni ó ti ń pa àwon èèyàn ìlú rè, ò n lò èro ayélujára tí ó pín àwòrán àti ìtàn yí jé kí ó di mímò wípé òun ni ó tilè pa ìyá tí ó bíi l’ómo. Arábìnrin kan pèlú omo rè mérin tí ó pa ni ó jé kí àsírí tú. Àwon ará ìlú mu yíká ìlú láti fi se èsin.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti