Home / Art / Àṣà Oòduà / Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)
ogogo

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won
ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba
tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji
ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere christ Church School
towa ni Ilaro nipinle ogun, leyin igbayen ni won losi
ilu Eko nibe naa ni wonsiti pari iwe alakobere won,
leyin nani won losi ile-we(technical School) lati lo
ko ise atun okose (Automobile Mechanic) leyin nani
won tesiwaju pelu sise pelu awon ajo olomi ero
(water coperation) tilu eko fun odun metala
(13years) nigbati odi odun 1981 ni won darapo mo
ise ere ori tage opolopo sinima ni wonti bawon kopa
ninu re, opolopo sinima lawon naa siti gbe jade,
beesini opolopo Ami eye ni wonsi tifi dawon lola pelu

About ayangalu

7 comments

  1. Segun Akerele

    ogogo omokulodo omo ku lomi lomi

  2. Gbolahan Sotomi

    Ajepe aye oooo. Opolo yin ko ni joba o

  3. Segun Akerele

    Emi gigun ati alafia ni emafilo ile aiye yin oo

  4. Kenny Fasemore

    Eku eto o,Olohun a ma lekun imo yin o, Ogogo omo kulodo a ri yin pe o, Ase

  5. Ewa yin o ni baje Ogogo Omo kulodo ajepe aye

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti