Home / Art / Àṣà Oòduà / Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.
Dbanj

Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.

Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó jé ilé-isé rè tí ó dá sílè nínú osù keje odún 2016 ni won ti ri wípé ó tó Dólà lónà ogóòrun mílíònù $100 million dollars èyí tí ó ju áárùndínlógójì bílíònù náírà lo tí a bá wò ó pèlú òsùwòn pàsípààrò. Ó ko pe:

 

Ojó keje osù keje odún 2017(7:7:17) Àfojúsùn tí ó bèrè ní inú ìwé ìròyìn ti wá sí ìmúse lóòní tí ó pé odún kan gérégé, láti ran àwon tí ó ní èbùn alátinúwá láti jé kí àfojúsùn won wá sí ìmúse káàkiri Nàìjíríà, léyìn odún kan tí ó ti di ònà tí mò ń wá láti odún 2012 . Ó ti gba Global Label Distribution Deal fún àwon èèyàn mi èbùn adúláwò (African talent) láti bí ilé-isé tí ó ń jé @DCREAMERECORDS tí won Sì ti ri wípé ó ju Dólà lónà ogóòrun mílíònù lo. Ìrèlè mi pò púpò : mo kàn fé dúpé lówó olórun, Ebí mi, Òré mi, ACS, alátakò àti àwon aláfowósowópò mi. Mo sì fé so fún yín wípé nínú ohun gbogbo kí á gba olórun gbó kí a sì gba ara eni gbó!
Attachments area

Continue after the page break for English Version

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Fifty-One with ‪@yemieleshoboodanuru589‬ #Yoruba #learnyoruba #yorubaculture