Home / Art / Àṣà Oòduà / Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e
Tony Blair

Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e

Olootu ile Biritiko nigba kan ri, Tony Blair, ti toro aforojin lowo gbogbo aye pelu bose lediapopo mo ijoba ile Amerika eleyii ti George Bush se adari fun lati fogun ja ile Iraq.
Alaye yii ni Ogbeni Tony se lori telisan agbaye. Bakan naa lo fi kun un wi pe oun lero wi pe ogun ti awon gbe ko Iraq lo sokunfa igbedide awon alakatakiti esin Islam, ISIS.

Tony ko sadeede toro aforojin, laipe yii ni won ri akosile kan lati ile ijoba ile Amerika eleyii to se afihan bi Tony ati Bush se mule lati fi iya je aare ile Irag, Saddam Hussein.

 

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria