Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán Adesua Etomi níbi ayeye ìgbéyàwó ìsènbáyé rè.

Àwòrán Adesua Etomi níbi ayeye ìgbéyàwó ìsènbáyé rè.

    Òsèré tí ó gbajúgbajà, Adesua Etomi tún yo ní àrà òtò, sé e mò wípé òtò l’omo oba n rìn . Ó ti è ti rewà jù òun gan ni a ò bá ma pè ní Òkín l’áwùjo omo eye, tí a kò bá ní p’aró egbin ni Adesua Etomi.

BankyW kò kúkú fi owó jóná.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti