Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon ajínigbé àti omo egbé òkùnkùn mérin ní ìpínlè River

Àwon ajínigbé àti omo egbé òkùnkùn mérin ní ìpínlè River

Àwon ajínigbé mérin tí won tún jé omo egbé òkùnkùn tí ńkó da ìjoba ìbílè Eleme àti agbègbè rè láàmú ni àwon olùbódàbòbò pa .

Orúko àwon tí won pa a máa jé Joe Mba tí ìnagije rè ńjé Sk tàbí Mba boy, Teetito frank tí ìnagije rè ńjé Obele,, Teetito Godwin tí ìnagije rè ńjé Coachy boy àti Gift Paul.

Ìsèlè yí sèlè ní fine real capital hotel ní ònà Okigwe ní ìjoba ìbílè Àríwà Owerri.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti