Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ti mú, tí won sì ti tì wón mó àgó olóòpá tí ó wà ní Moore .

Ó máa wà nínú àkosílè wípé ní ojó kàrún osù kewàá odún 2017 (5/10/2017) ni àwon akékòó se àtakò àláfíà látàrí ohun èlò tí kò sí ní inú Ogbà. Ní ojó kejì àtakò yí, àwon ìgbìmò ìdábòbò ilé-èkó yí sáré lo sí ààrin àwon akékòó yí tí won sì mú méwàá nínú won, tí igbákejì ààre akékòó ifáfitì yí “Jacob Tosin(Emerald)”sì wà láàrin won…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti