Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni tí kò ní opolo.
Kò kúkú sí ohun tí a kò ní rí tán, kárí kâ fojú fò lópò, àfi kí olórun gbà wá.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

