Òrò tí ó gbòde kan ni wípé Chidinma Ekile ti darapò mó egbé burúkú àti wípé ó ti n kégbékégbé látàrí wípé ó ya tàtúù dí èyìn rè .
Chidinma Ekile níbi ayeye kan tí ó wo aso tí ó sí èyìn sílè èyí tí ó gbé àwòrán tí ó yà sí èyìn rè jáde, tí ó sì ya òpò lénu sùgbón àríyànjiyàn ti wà wípé làálì lásán làsàn ni sùgbón àwon kan ta ko èyí.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

