Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .

Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .

      Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ni ó wà n’íbè bíi Rick Ross, Diddy , Monika Brown àti oko rè, Big Sean àti Jhene Aiko, Zchaizz , lil Yachty àti ìyá rè àti òpòlopò àwon ènìyàn míràn ni ó péjú n’íbè…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti