Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

      Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra . 

  Àwon òré àti aféniféni ni won péjú p’ésè níbè láti fun ní ìbòwò ìkeyìn tí ó jé wípé àwon olùdábòbò sì n se ìwádìí ikú tí ó pa á….

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti