Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

   Isé rí èro ayélujára n se kojá òye èdá…

Àwon oko pèlú Aya àfésónà yí ti setán láti di tokotayà ní òsè péréte si léyìn tí won làdé lórí èro ayélujára (Facebook). Gégé bí Ijeoma Nwosu se so, ó ní òun pàdé olólùfé òun Chukwuma Inya-Agha ní odún méta séyìn léyìn ìgbà tí ó ka èróngbà àwon èèyàn lórí oun tí ó pín ní orí (Facebook).
Báyìí won ti se tán àti féra ní ojó kesàn-án osù kejìlá (9/12/2017).

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti