Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.

    Nígbà tí mo rí àwòrán yí ní orí èro ayélujára , mo kókó dúró ná mo wá bi ara mi ní ìbéèrè wípé kíni obìnrin fé nínú ìgbéyàwó tàbí lára okùnrin ? Léyìn òpò ìrònú àti òpò ìrírí mo wá pa okàn pò wípé ogún-l’ógbòn àwon obìnrin ní ó fé ìfé òtító àti òdodo, ngbó èyin okùnrin kìí se gbogbo obìnrin ni ó fé owó yín bí kò se ìfé òtító ni won n wá .

Ìdùnnú eyòkan ló wà, òun ni kí ènìyàn méjì níìfé ara won, àwòrán yí ní àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó àwon tokotayà yí, oko aràrá àti ìyàwó rè tí ó rèwà.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti