Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn .
Àwòrán ti aya tí ó n bò lónà àti oko rè, tí ìyàwó jé olùwòsàn tí oko sì jé olópàá yí mà rewà púpò jú o.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


One comment
Pingback: Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn. – Naija Curator