Obafemi Awolowo tí ó jé ògbóntarìgì àti adarí àwon olósèlú, tí ó sì kó iPa takuntakun láti jé kí orílè èdè yí di olómìnira.
Làra àwon ohun tí ó wà ní ibi tí won kó nkan ìsèńbáyé sí tí a mò sí Museum, ni okò tí a mò sí Mercedes 230:6.
Okò yí ni Awolowo lò láti fi se ìponlogo àti láti fi rin gbogbo ìrìn àjò ní odùn 1979 àti 1983, tí okò náà jé ríra ní odún 1970….
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

