Àwòrán Olusegun Obasanjo tí ó yà ní ìgbà tí ó ti pé tí ó yà ní kété tí won fi sílè ní èwòn.
Olusegun Obasanjo níbi ìsìn ìdúpé léyìn ìgbà tí won da sílè l’éwon ní odún 1998. Owó mà da lára o, sé èèyàn le mò wípé baba rèé.
Yínká Àlàbí Awọn kọmiti to n ṣe àyẹ̀wò awọn oludije du ipo gomina labẹ ẹgbẹ́ oselu APC ti ja igbakeji gomina tẹlẹ ni ipinle Osun, Alagba Iyiola Omisore ati awọn mẹfa miiran.Wọn ni iwe wọn ko pe lati dije du ipo gomina ipinlẹ naa. Awọn mẹfẹẹfa to ku naa ni – Babatunde Oralusi, Oyedotun Babayemi, Dr. Akin Ogunbiyi, Benedict Alabi, Adegoke Rasheed Okiki, ati Senator Babajide Omoworare.Iyiola Omisore ni awada Kẹri-Kẹri ni awọn kọmiti naa n se nitori ti wọn ...