Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
Ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ọjọ́ òní – Èse Ọrọ miiran fun Èse ni Ológìní, Músù tabi Ológbò Yoruba word of the day: Èse Another word in Yorùbá for Èse (Cat) is Ológìní, Músù or Ológbò.