Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán omo odún mókàndínlógún (19) tí won mú pèlú orísirísi èyà ara ní Awka.

Àwòrán omo odún mókàndínlógún (19) tí won mú pèlú orísirísi èyà ara ní Awka.


Gégé bí ìròyìn se so, won ti fi ìgò gún omo odún mókàndínlógún (19) yánmayànma látàrí àwon èyà ara tí won bá ní owó rè, won bá omoníka àti ojú ara omo odún mérin okùnrin ní Awka, ìpínlè Anambra.
Afura sí náà, tí a mò sí Ògbéni Sunday Onwebenyi láti Emeziaka Mgbo ní ìjoba ìbíle Ohaukwu ní Ìpínlè Ebonyi, tí ó jéwó wípé òun pa omo náà pèlú àwon afura sí míràn ní ibì kan nàà.
Èyí selè nígbà tí òré bìnrin láti agbègbè kan náà tí n jé, omidan Blessing Eze, ni ó ti so fún kí ó lo sí àdúgbò kan ní ìlú Awka, níbi tí owó ti tè é, èróngbà won ni láti tún rí owó púpò si.
Won ti fáà fún àwon olópàá fún Ìwàdìí tí ó tó.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...