Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon onísé abe; bàbá kan ní orílé èdè Nàíjíríà àti omo rè obìnrin ti se isé abe lórí aláìsàn won .

Àwon onísé abe; bàbá kan ní orílé èdè Nàíjíríà àti omo rè obìnrin ti se isé abe lórí aláìsàn won .

Ò n lò èro ayélujára (Facebook) Bucandy Ayo Abubakar, tí ó jé onísé abe pín àwòrán ara rè àti bàbá rè àti bàbá rè onísé abe ti se isé-abe fún aláìsàn kan tí ó ní àìsàn “Appendix” ó sì ko síbè wípé .
“Nígbà tí bàbá re bá jé onísé abe ti ìwo náà sì jé ìgbákejì rè”.
Omo Àjànàkú kò le yàrá omo tí eyá bá bí eyá ní jo.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti