Home / Art / Àṣà Oòduà / Tunde Demuren, Ebuka àti ìyàwó rè ti wo okò òfurufú (jet) láti lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W.

Tunde Demuren, Ebuka àti ìyàwó rè ti wo okò òfurufú (jet) láti lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W.

Gbajúgbajà ni, òtòkùlú ni, captain Tunde Demuren tí ìnagije rè n jé OAP, oko toolz ti gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán yí nígbà tí won wo okò òfurufú lo sí Capetown láti péjú pésè níbí ayege ìgbéyàwó aláréde ti Banky W àti Adesua Etomi.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Àwọ̀ ni Édè Yorùbá

Àwọ̀ ni Édè Yorùbá – Colours in Yoruba Language

Dúdú – BlackÀwọ̀ Ojú Ọ̀run – BlueÀwọ̀ igi – BrownÀwọ̀ Eérú – GrayÀwọ̀ Ewé – GreenÀwọ̀ Òféfèé – OrangePupa – RedFunfun – WhitePupa rusurusu – YellowÀwọ̀ dúdú – Dark colorLight color: Àwọ̀ tí ó mọ́lẹ̀Colors: Àwọn àwọ̀  Ojú Ọ̀run dúdú díẹ̀ – The sky is blueOlógbò rẹ funfun – Your cat is white Àwọ̀ dúdú ní ó yàn láàyò – Black is his favorite colorÀwọ̀ pupa kì íṣe èyí tí ó yàn láàyò – Red is not his favorite colorÓ nwà ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ...