Àwon ìgbìmò tuntun rè é, Gómìnà ìpínlè River, Nyesom Ezenwo Wike tètè dé sí Ilorin ní ìpínlè Kwara fún ìpàdé pàtàkí náà pèlú àwon ti Benue náà, Gómìnà Samuel Ortom tí ó sèsè ko ìwé láti fi egbé APC sílè fún èyí tí a kò tí mò.
Sineto George Sekibo, Sineto Adawari pepple àti àwon míràn ni ó sin Gómìnà Wike lo sí ibi ìpàdé náà.
Àwon Gómìnà méjèèjì ti se ìpàdé pèlú Sineto Bukola Saraki àti Gómìnà ìpínlè Kwara, Abdul Fatah Ahmed.
 
		 Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more