Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.
Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò.
Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde Dasilva náà wo èyìn wò nígbà tí ó pín àwòrán ìgbà èwe rè sì orí èro ayélujára insítágírámú.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


