Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán tí ìyá rè pín sí orí èro ayélujára.
Ọ̀rọ̀ Yorùbá ti ọjọ́ òní – Èse Ọrọ miiran fun Èse ni Ológìní, Músù tabi Ológbò Yoruba word of the day: Èse Another word in Yorùbá for Èse (Cat) is Ológìní, Músù or Ológbò.