Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon tí won ti yo kúrò àti àwon tí won lé ní BBNaija ti se àyéwò sí ilé-ìfowópamó tí a mò sí Heritage bank.

Àwon tí won ti yo kúrò àti àwon tí won lé ní BBNaija ti se àyéwò sí ilé-ìfowópamó tí a mò sí Heritage bank.

    Àwon Alábagbélé àti olùgbépò télè ti big brother Naija, àwon tí a mò sí Vandora, Princess, Dee one , Bitto àti àwon tí won lé kúrò Khloe àti k Brule se àbèwò sí ìkan lára àwon ilé-isé tí ó rán wón lówó láti gbé won ga .

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...