Oni ojo kokanlelogun, osu kejo (Aug 21), odun 2015 ni Gomina Abiola Ajimobi n se igbeyawo fun omo re obirin, Ajibola pelu oko omo re, Ayokunle Olayiwola.
Orisirisi awon eniyan nlanla ati awon gomina lati apa iwo-oorun guusu Naijeria ni won ti pejupese sibe. Omo Baba Olowo, Davido ati Olamide ko si dake orin lati maa fi da awon eniyan lara ya.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more






