Home / News From Nigeria / Breaking News / Awon ojo ile Yoruba (Yoruba Days Of The Week)
Oloye Yemi Elebuibon

Awon ojo ile Yoruba (Yoruba Days Of The Week)

Oloye Yemi Elebuibon, The Araba of Osogbo, tells us about the Yoruba days of the week and their origin. Tunde Kelani is known for his great movies such as Saworo Ide, Agogo Eewo, Oleku, Ti Oluwa nile, etc.

Ọjọ́ Àìkú – Sunday (Day of not dying)
Ọjọ́ Ajé – Monday (Day of profit)
Ọjọ́ Ìṣẹ́gun – Tuesday (Day of victory)
Ọjọ́-rírú/Ọjọ́rú – Wednesday (Day of confusion or day of sacrificing)
Ọjọ́bọ̀/Ọjọ́ Àṣẹ̀ṣẹ̀ Dáyé – Thursday (Day of coming or day of recent creation)
Ọjọ́ Ẹtì – Friday (Day of failure)
Ọjọ́ Àbá Mẹ́ta – Saturday (Day of three suggestions)

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...