Home / Art / Àṣà Oòduà / Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.

Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.

  1.    Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ní pé dé…Èrín pa mí …n se ni ó dàbí àjòdún ère.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti