Home / Art / Àṣà Oòduà / Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
olojo ibi

Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo

Ododun larorogbo
Ododun lari awusa
Ododun lati mo obi lori ate
Ododun ni sapo nruwe
Ododun ni peregun yio
Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia
Alekun ogbon
Alekun Oye
Alekun IMO
Alekun emi gigun
Alekun Alaafia
Oju asa ki i ribi
Tawodi ki i roran
Leyi toku teo lo laiye oju yin oni ribi
Lagbara Olodumare ao jo peju se teemi ni
Ema farabale last bi HOLY BIBLE ni.
Igba Odun Odun kan nio……. IRE OOO

 

 

King Ogulutu Oro‎

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti