Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren . Banky W àti òré rè tímótímó fún ìgbéyàwó alárédè rè, Tunde Demuren ni won Jo ya àwòrán papò níbi ìgbéyàwó alárinrin ni won sì se jómírégí papò.
Èyí wù mí.
Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...