Home / Art / Àṣà Oòduà / Banky W àti Adesua Etomi fi enu ko ara won lénu níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè won ní orílè èdè South Africa .

Banky W àti Adesua Etomi fi enu ko ara won lénu níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè won ní orílè èdè South Africa .

” O le wá fi enu ko ìyàwó lénu báyìí” ni ó ma n dùn jù nínú ìgbéyàwó, tí kò bá rí béè Banky W àti Adesua kò bá má se tó báyìí, won ti fi enu ko ara lénu jù tí àwon àlejò fi so wípé ó ti pòjù, tí won fi pariwo wípé “ó ti tó”.
Èyí le múni ronú o .
Tokotayà tí ó rewà yí kí ara won.

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. Emi yin a guun oo.. Ase

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti