Home / Art / Àṣà Oòduà / Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí egbé yàn láti lo fún Gómìnà ìpínlè won ní Osun, Seneto Ademola Adeleke tí ìlú ede ní ìpínlè Osun.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti