Home / Art / Àṣà Oòduà / Davido, Gbajúgbajà olórin tí ó tún jé omo ebí Adeleke wo agbádá tí àwon egbé oní Àsìá se tí won sì ko orúko egbé won si.

Davido, Gbajúgbajà olórin tí ó tún jé omo ebí Adeleke wo agbádá tí àwon egbé oní Àsìá se tí won sì ko orúko egbé won si.

Olórin, tí ó tún jé òtòkùlú ti n se isé takuntakun láti ri dájú wípé, sínétò Ademola Adeleke di Gómìnà ìpínlè Òsun ní ibi ìdìbò tí ó n bò ní ojó àbáméta yí.

Ó tí è ti n sisé takuntakun láti polongo fún egbé PDP fún ègbón rè tí ó fé lo fún ipò gómìnà ní ojó àbámétà .
Èyí ni àwòrán ibi tí ó ti wo aso PDP fún Òsogbo ní ibi tí ó ti n polongo.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...