Home / Art / Àṣà Oòduà / E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?
owe

E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu.

E seun.

About ayangalu

6 comments

  1. EP ?

    Ile la n wo, ka to somo loruko

  2. EP ?

    Ile Oba to Jo, ewa lo bu si

  3. CHEN FU ? ?

    Ile oloke meje kose fii bomode sere…..

  4. Sawyerr

    Ile ni apoti n joko de idi

  5. Smithian

    Ile la tin kesho ro dé

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti