Home / Art / Àṣà Oòduà / E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..
omo yoruba

E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..

OOOOOOO
Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ekeji mi naa n je Kehinde, Obinrin nii . . . . ., Omo ipinle Ogun ni wa. Ki a pa ti Egan ti awa mejeeji r’ewa l’omo, a si mon iwe daadaa, sugbon ni nnkan bi Odun mesan seyin ni isele yi sele si emi ati Kehinde mi. Okan ninu awon ore wa lo n se ajodun ojo ibi re ni ilu Abeokuta, ojo naa je ojo Abameta, awa mejeeji mura, a si lo sibe, ibi ajodun ojo ibi naa pinmirin, gbogbo nnkan ti enu n je lo wa nibe, bee ni oti mimu naa ko gbeyin nibe, hummmmm, o ma se ooooo ????

Emi pelu Kehinde mi, ko si nnkan ti a ko je tabi mu ni ojo naa, a mun oti yo, nigba ti o di ale, inu Yara Kan naa ni awa mejeeji sun, ka ma fa oro gun, ninu yara yi ni mo ti gba ibale Kehinde mi, Ni ojo keji ki a to kuro ni Abeokuta, a tun sere ife bi eemeji, gbogbo akoko yi, Ile iwe Girama la wa, a si sese le die ni Omo odun mejidinlogun ni. Kere kere be be, awa mejeeji di ore kori ko sun, a ki i fe lo si ibi kibi, la mu ara wa dani, n ko gba ki Okunrin miran sun mon Kehinde mi, bee ni Kehinde naa ko fi aaye sile ki n ni Obinrin miran ni ore.

Bi awon obi wa ba ti jade tabi won rin irin ajo, ise bere laarin wa niyen, o de akoko Kan ti o je pe yara Kehinde ni mo maa n sun, tabi ki Kehinde wa sun yara mi, se awon obi wa ro pe ife lbeji lasan lo wa laarin wa ni, lai mon pe ife l’oko l’aya ni a n se. Nigba ti a pari ni Girama, a gbiyanju lati te siwaju ninu Eko wa, won mu emi si Yunifasiti lbadan, nigba ti won mu Kehinde si Yunifasiti Uyo ti Eka re wa ni Ilu lla Orangun, awa mejeeji fi dandan le e fun awon obi wa pe ki a wa ni Ile iwe Kan naa, mo tun jeki lya mi mon pe llu lla Orangun ti Jina fun Kehinde gege bi Omobinrin ti ko jade kuro ni Abe awon obi re ri. Iya mi ronu si oro naa, o pe akiyesi Baba mi si i, won sise lori re, awa mejeeji si jo wa ni Ilu lbadan fun Eko wa.

Nibi yi ni aaye ti gba wa, se ko kuku si Eni ti a so fun pe tegbon taburo ni wa nibi ti a n gbe, inu yara Kan la n gbe yara yi ni Ile iwe ati Ile iyagbe papo, emi pelu Kehinde jo n we papo ni, ko si asiri kankan ni aarin wa. Gbogbo awon ti won n ri wa lo mon wa bi l’oko l’aya ojo iwaju, eyi ko fun mi laaye lati ni ore binrin, bee ni Kehinde naa ko ni ore kunrin, Ni ojo Kan, a lo sibi odun ibile Kan ni Ondo, a tele ore wa Kan ti o je Omo Babalawo lo, nibe ni ore mi ti gba wa ni iyanju pe ki emi pelu Kehinde se imule gege bi l’oko l’aya ojo ola, se oye imule naa ko kuku ye wa daadaa, a ko si fe ki o han si ore wa pe ibeji ni awa mejeeji.

A se imule pe ao je olooto si ara wa ati pe, a ko ni dale ara wa gege bi l’oko l’aya. O ma se ooooo. Ni bayi awa mejeeji ti jade Ile iwe, a wa ni Ilu Eko, a ti ni ise ti o dara lowo, gbogbo Igba to ba wu wa ni a n sere ife. Ni bayi, Odun yi lo pe odun mesan ti emi pelu Kehinde mi ti n ba ara wa sere ife, awon obi wa ti dagba, Koda, ldowu wa ti se igbeyawo alarinrin, o si ti bi Omo meji, ojoojumo ni awon obi wa n so fun wa pe ki emi ati Kehinde mu Eni ti a fe fe wa sile , sugbon imule ti a se n ba wa lara, ati pe n ko ri obinrin naa ti o le dabi Kehinde ninu aye mi, gege bi nnkan ti a gbo ki a to pari ni Ile iwe ni pe Baba ti o se imule fun wa ni Ondo ti ku. E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ooooooooooo

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Seventy-three: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture